Ileeṣẹ ọlọpaa ti kede pe ọga ọlọpaa ẹkun Bwari niluu Abuja nibi tawọn ajinigbe ti gbe baba ati ọmọ mẹfa lọ, ASP Audu Mohammed, si n gba itọju lọwọ nile iwosan lara to fara gbọta awọn ajinigbe.
Iya ọmọkunrin ọmọ ọdun meje ti baba rẹ sin laaye nipinlẹ Enugu, sọ pe ibanujẹ nla ni iṣẹlẹ naa jẹ fun oun. Arabinrin Onyishi sọ fun BBC Igbo ninu ifọrọwanilẹnuwo pe oun ko fi igba kankan fura pe ọkọ ...
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results