Awọn mọlẹbi ọga agba ileeṣẹ ọmọ ogun Naijiria to di ologbe, Taoreed Lagbaja ti n daro ipapoda rẹ. Nigba ti BBC Yoruba ṣabẹwo si ilu Ilobu, to jẹ ilu ibilẹ oloogbe naa, niṣe lawọn mọlẹbi rẹ n wa ẹkun ...