Ileeṣẹ ọlọpaa ti kede pe ọga ọlọpaa ẹkun Bwari niluu Abuja nibi tawọn ajinigbe ti gbe baba ati ọmọ mẹfa lọ, ASP Audu Mohammed, si n gba itọju lọwọ nile iwosan lara to fara gbọta awọn ajinigbe.
Aarẹ ẹgbẹ awọn oṣere tiata labẹ aṣia ẹgbẹ Association of Nigerian Theater Arts Practictioners, ANTP, Alagba Adewale Ẹlẹshọ, ti ọpọ mọ si Elesho ẹnu n ja waya, naa ti da si ọrọ Baba Ijẹṣa bayii. Ninu ...